Joel 2:32

32 aYóò sí ṣe, ẹnikẹ́ni tí ó ba ké pè
orúkọ Olúwa ní a ó gbàlà:
nítorí ní òkè Sioni àti ní Jerusalẹmu
ní ìgbàlà yóò gbé wà,
Olúwa ti wí,
àti nínú àwọn
ìyókù tí Olúwa yóò pè.
Copyright information for YorBMYO